Saamu
<
117
>
Saamu 117
1
Ẹ yin
Olúwa
, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;
ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.
2
Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa,
àti òtítọ́
Olúwa
dúró láéláé.
Ẹ yin
Olúwa
!
Saamu
<
117
>
© 2009, 2017 Biblica